Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wò ó, mo rí ohun kan tó dàbí òkúta sáfírè nínú òfuurufú tó wà lókè orí kérúbù, ìrísí ohun yìí sì dàbí ìtẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:1 ni o tọ