Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọjọ́ ìjìyà ń bọ̀;Àwọn ọjọ́ ìṣirò iṣẹ́ ti déJẹ́ kí Ísírẹ́lì mọ èyíNítorí pé ẹ̀ṣẹ̀ yín pọ̀ìkórìíra yín sì pọ̀ gan an ni.A ka àwọn wòlíì sí òmùgọ̀A ka ẹni ìmísí sí asínwín.

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:7 ni o tọ