Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò ní fi ọrẹ ohun mímu fún Olúwa.Bẹ́ẹ̀ ni ìrúbọ wọn kò ní mú, inú rẹ̀ dùn.Ìrú ẹbọ bẹ́ẹ̀ yóò dàbí oúnjẹ àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀.Gbogbo àwọn tó bá sì jẹ ẹ́ yóò di aláìmọ́.Oúnjẹ yìí yóò wà fún wọn fúnra wọnkò ńi wá sí orí tẹ́ḿpìlì Olúwa

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:4 ni o tọ