Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí mo rí Ísírẹ́lì,Ó dàbí ìgbà tí ènìyàn rí èso àjàrà ní ilẹ̀ aṣálẹ̀Nígbà tí mo rí àwọn baba yín.Ó dàbí ìgbà tí ènìyàn rí àkọ́so èso lórí igi ọ̀pọ̀tọ́ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n dé ọ̀dọ̀ Baali-PéórìWọ́n yà wọn sọ́tọ̀ fún òrìṣà tó ń mú ìtìjú bá niwọ́n di aláìmọ́ bí ohun tí wọ́n fẹ́ràn.

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:10 ni o tọ