Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe yọ̀, ìwọ Ísírẹ́lì;má ṣe hó ìhó ayọ̀ bí àwọn orílẹ̀ èdè yòókù.Nítorí ẹ ti jẹ́ aláìsòótọ́ si lọ́run yín.Ẹ fẹ́ràn láti gbowó iṣẹ́ àgbèrèní gbogbo ilẹ̀ ìpàkà.

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:1 ni o tọ