Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wọ́n gbin afẹ́fẹ́wọ́n sì ká ìjìIgi ọkà kò lórí,kò sì ní mú oúnjẹ wá.Bí ó bá tilẹ̀ ní ọkààwọn àlejò ni yóò jẹ.

Ka pipe ipin Hósíà 8

Wo Hósíà 8:7 ni o tọ