Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ní fún wọn,nítorí pé wọ́n ti yà kúrò lọ́dọ̀ mi!Ìparun wà lórí wọn,nítorí pé wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi!Èmi yóò rà wọ́n padà.Ṣùgbọ́n wọ́n ń parọ́ mọ́ mi

Ka pipe ipin Hósíà 7

Wo Hósíà 7:13 ni o tọ