Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí èmi ìbá mú Ísírẹ́lì láradá.Ẹ̀ṣẹ̀ Éfúráímù ń farahànìwà búburú Ṣamáríà sì ń hàn sítaWọ́n ń ṣe èrúàwọn olè ń fọ́ iléàwọn ọlọ́ṣà ń jalè ní òpópónà

Ka pipe ipin Hósíà 7

Wo Hósíà 7:1 ni o tọ