Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n kí ẹnikẹ́ni má ṣe mú ẹ̀sùn wá,kí ẹnìkan má sì ṣe fi ẹ̀sùn kan ẹ̀nìkéjìnítorí àwọn ènìyàn rẹ̀ dàbíàwọn ti ń fi ẹ̀sùn kan àlùfáà

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:4 ni o tọ