Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àìṣe bẹ́ẹ̀ èmi yóò tú u sí ìhòòhòÈmi yóò sì gbé e kalẹ̀ lá ìwọṣọ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí a bí i.Èmi yóò ṣe ọ́ bí i aṣálẹ̀ ilẹ̀,Èmi yóò sì sọ ọ́ di ìyàngbẹ ilẹ̀Èmi yóò sì fi òùngbẹ gbẹ ẹ́.

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:3 ni o tọ