Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ bá ìyáa yín wí, ẹ bá a wí,nítorí pé kì í ṣe ìyàwó mi,Èmi náà kì í sì í ṣe ọkọ rẹ̀.Jẹ́ kí ó yọ àgbèrè rẹ̀ kúrò lójú rẹ̀àti àìsòótọ́ kúrò ní àyà rẹ̀.

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:2 ni o tọ