Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó sì gbìn-ín fún ara mi lórí ilẹ̀ náàÈmi yóò ṣàánú fún ẹni tí kò tì í ri ‘àànú Gbà.’Èmi yóò sọ fún àwọn tí ‘Kì í ṣe ènìyàn mi pé,’‘Ẹ̀yin ni ènìyàn mi’; àwọn náà yóò sì wí pé, ‘Ìwọ ni Ọlọ́run mi.’ ”

Ka pipe ipin Hósíà 2

Wo Hósíà 2:23 ni o tọ