Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báwo ni èmi ó ṣe fi ọ́ sílẹ̀, Éfúráímù?Báwo ni èmi ó ṣe yọ̀ǹda rẹ̀, Ísírẹ́lìBáwo ni mo ṣe lè ṣe ọ bi i Ádímà?Báwo ni mo ṣe lè ṣe ọ bi i Ṣébóímù?Ọkàn mi yípadà nínú miÀánú mi sì ru sókè

Ka pipe ipin Hósíà 11

Wo Hósíà 11:8 ni o tọ