Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ṣe ìlérí púpọ̀,wọ́n ṣe ìbúra èké,wọ́n da májẹ̀mú:báyìí ni ìdájọ́ hù sókè bí igi ìwọ̀ ni aporo oko,bi i koríko májèlé láàrin oko tí a ro.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:4 ni o tọ