Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísírẹ́lì jẹ́ igi àjàrà tó gbaléó ń sọ èṣo fún ara rẹ̀Bí èso rẹ̀ ṣe ń pọ̀bẹ́ẹ̀ ni ó ń kọ́ pẹpẹ sí ibí ilẹ̀ rẹ̀ ṣe ń ṣe rereÓ bu ọlá fún òkúta ìyàsọ́tọ̀ ère rẹ̀.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:1 ni o tọ