Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀, èmi yóò ṣàáànú fún ilé Júdà, èmi ó gbà wọ́n—kì í ṣe nípa ọfà, idà tàbí ogun, ẹṣin tàbí kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin bí kò ṣe nípa Olúwa Ọlọ́run wọn.”

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:7 ni o tọ