Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Olúwa sọ fún Hósíà pé, “Pe orúkọ ọmọ náà ní Jésírẹ́lì, nítorí pé láìpẹ́ ni èmi yóò jẹ ìdílé Jéhù ní ìyà fún ẹ̀jẹ̀ àwọn ènìyàn tó pa ní ìpakúpa ní Jésírẹ́lì, Èmi yóò sì mú ìjọba Ísírẹ́lì wá sí òpin.

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:4 ni o tọ