Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hágáì 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò bi ìtẹ́ àwọn ìjọba ṣubú, Èmi yóò sì pa agbára àwọn aláìkọlà run; Èmi yóò sì dojú àwọn kẹ̀kẹ́ ogun dé, àti àwọn tí ń gùn wọ́n; ẹṣin àti àwọn ẹlẹ́sin yóò ṣubú; olúkúlùkù nípa idà arákùnrin rẹ̀.”

Ka pipe ipin Hágáì 2

Wo Hágáì 2:22 ni o tọ