Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hágáì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ fún Sérúbábélì ọmọ Séítélì, olórí Júdà, àti Jóṣúà ọmọ Jósédékì, olórí àlùfáà àti àwọn ènìyàn yòókù. Béèrè lọ́wọ́ wọn pé,

Ka pipe ipin Hágáì 2

Wo Hágáì 2:2 ni o tọ