Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ìwọ ha ń bínú sí àwọn Odò nì, Olúwa?Ǹjẹ́ ìbínú rẹ wa lórí àwọn odò síṣàn bí?Ìbínú rẹ ha wá sórí òkuntí ìwọ fi ń gún ẹṣin,àti kẹ̀kẹ́ ìgbàlá rẹ?

Ka pipe ipin Hábákúkù 3

Wo Hábákúkù 3:8 ni o tọ