Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 3:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Ó dúró, ó sì mi ayé;ó wò, ó sì mú àwọn orílẹ̀-èdè wárìrìa sì tú àwọn òkè-ńlá ayérayé ká,àwọn òkè kéékèèkéé ayérayé sì tẹríba:ọ̀nà rẹ ayérayé ni.

7. Mo rí àgọ́ Kúṣánì nínú ìpọ́njúàti àwọn ibùgbé Mídíanì nínú ìrora.

8. Ǹjẹ́ ìwọ ha ń bínú sí àwọn Odò nì, Olúwa?Ǹjẹ́ ìbínú rẹ wa lórí àwọn odò síṣàn bí?Ìbínú rẹ ha wá sórí òkuntí ìwọ fi ń gún ẹṣin,àti kẹ̀kẹ́ ìgbàlá rẹ?

Ka pipe ipin Hábákúkù 3