Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbogbo àwọn wọ̀nyí kì yóò máa pa òwe sí i tí wọn yóò sì máa kọ orin òwe sí i wí pé,“ ‘Ègbé ni fún ẹni tí ń mu ohun tí kì í ṣe tirẹ̀ pọ̀ sí i!Tí ó sì ṣọ ara rẹ̀ di ọlọ́rọ̀ nípaṣẹ̀ ìlọ́nilọ́wọ́ gbà!Eléyìí yóò ha ti pẹ́ tó?’

Ka pipe ipin Hábákúkù 2

Wo Hábákúkù 2:6 ni o tọ