Nítorí pé, èmi yóò gbé àwọn ara Bábílónì dìde,àwọn aláìláàánú àti onínú fùfù ènìyàntí ó rin gbogbo ilẹ̀ ayé jáláti fi agbára gbà àwọn ibùgbé tí kì í ṣe ti wọn.