Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hábákúkù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ wo ìnú àwọn aláìkọlà, ki ẹ sí wòye,Kí ìyàlẹnu kí o sí ṣe yin gidigidiNítorí tí èmi yóò ṣe ohun kan ni òwúrọ̀ ọjọ́ ọ yíntí ẹ̀yin kì yóò sì gbàgbọ́bí o tilẹ̀ jẹ́ pé a sọ fún un yin.

Ka pipe ipin Hábákúkù 1

Wo Hábákúkù 1:5 ni o tọ