Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 9:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A gbọdọ̀ máa ṣe ìrántí àwọn ọjọ́ wọ̀nyí kía sì máa pa wọ́n mọ́ ní ìrandíran ní gbogbo ìdílé, àti ní gbogbo ìgbèríko àti ní gbogbo ìlú. A gbọdọ̀ máa ṣe àwọn ọjọ́ Púrímù wọ̀nyí ní ìgbà gbogbo bẹ́ẹ̀ ni kò gbọdọ̀ di ohun ìgbàgbé láàrin irú àwọn ọmọ wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:28 ni o tọ