Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí, kọ ìwé àṣẹ mìíràn ní orúkọ ọba bí àwọn Júù ṣe jẹ́ pàtàkì sí ọ, kí o sì fi òrùka ọba ṣe èdìdì dìí-nítorí kò sí àkọsílẹ̀ tí a bá ti kọ ní orúkọ ọba tí a sì fi òrùka ọba ṣe èdìdì tí a lè yìí padà.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:8 ni o tọ