Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ìgbèríko àti ní gbogbo ìlú, ní gbogbo ibi tí àṣẹ ọba dé, ni ayọ̀ àti inú dídùn ti wà láàrin àwọn Júù, wọ́n sì ń ṣe àsè àti àjọyọ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìlú tó kù sọ ara wọn di Júù nítorí ẹ̀rù àwọn Júù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:17 ni o tọ