Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn ìwé àṣẹ náà ni kí a gbé jáde gẹ́gẹ́ bí òfin ní gbogbo ìgbéríko kí ẹ sì jẹ́ kí ó di mímọ̀ fún gbogbo ènìyàn ìlú nítorí àwọn Júù yóò leè múra ní ọjọ́ náà láti gbẹ̀san fún ara wọn lára àwọn ọ̀taa wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:13 ni o tọ