Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àṣẹ ọba sì dé ọ̀dọ̀ àwọn Júù ní gbogbo ìlú láti kó ara wọn jọ kí wọn sì dáàbò bo ara wọn; láti pa, láti run àti láti kọlu ogunkógun orílẹ̀ èdè kórílẹ̀ èdè kankan tàbí ìgbéríko tí ó bá fẹ́ kọ lù wọ́n, àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ wọn; kí ẹ sì kó gbogbo ohun ìní àwọn ọ̀taa wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:11 ni o tọ