Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kan náà ni ọba Ṣérísésì fún Ésítà ayaba ní ilée Hámánì, ọ̀ta àwọn Júù. Módékáì sì wá síwájú ọba, nítorí Ẹ́sítà ti sọ bí ó ṣe jẹ́ sí ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:1 ni o tọ