Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru ọjọ́ náà ọba kò le è ṣùn; nítorí náà, ó pàṣẹ kí wọn mú ìwé ìrántí wá, àkọsílẹ̀ ìjọba rẹ̀, wọ́n mú un wá wọ́n sì kàá síi létí.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 6

Wo Ẹ́sítà 6:1 ni o tọ