Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hámánì jáde lọ ní ọjọ́ náà pẹ̀lú ayọ̀ àti inú dídùn. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó rí Módékáì ní ẹnu ọ̀nà ọba, ó wòye pé kò dìde tàbí kí ó bẹ̀rù ní iwájú oun, inú bí i gidigidi sí Módékáì.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:9 ni o tọ