Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọba bá fi ojú rere rẹ̀ fún mi, tí ó bá sì tẹ́ ọba lọ́rùn láti gba ẹ̀bẹ̀ mi àti láti mú ìbéèrè mi ṣẹ, jẹ́ kí ọba àti Hámánì wá ní ọ̀la sí ibi àṣè tí èmi yóò pèṣè fún wọn. Nígbà náà ni èmi yóò dáhùn ìbéèrè ọba.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:8 ni o tọ