Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hámánì gbéraga sí wọn nípa títóbi ọ̀rọ̀ rẹ̀, púpọ̀ àwọn ọmọ rẹ̀, àti gbogbo ọ̀nà tí ọba ti bu ọla fún-un àti bí ó ṣe gbé e ga ju àwọn ọlọ́lá àti àwọn ìjòyè tó kù lọ.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:11 ni o tọ