Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 4:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́bìnrin àti àwọn ìwẹ̀fà Ẹ́sítà wá, wọ́n sọ nípa Módékáì fún-un, ó sì wà nínú ìbànújẹ́ ńlá. Ó fi aṣọ ránṣẹ́ síi kí ó wọ̀ ọ́ dípò aṣọ ọ̀fọ̀ tí ó wọ̀, ṣùgbọ́n òun kò gbà wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:4 ni o tọ