Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbogbo ìgbèríko tí ikú àti àṣẹ ọba dé, ọ̀fọ̀ ǹlá dé bá àwọn Júù, pẹ̀lú ààwẹ̀, ẹkún àti ìpohùn réré ẹkún. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ wà ninú aṣọ ọ̀fọ̀ tí wọ́n fi eérú kúnra.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:3 ni o tọ