Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ìwọ jẹ́ olódodo O dá wa sí lónìí bí àwọn tí ó ṣẹ́kà. Àwa nìyí níwájú rẹ nínú ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ wa, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé nítorí rẹ̀ ẹyọ ẹnìkan kò lè dúró níwájú rẹ.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 9

Wo Ẹ́sírà 9:15 ni o tọ