Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

èyí tí ìwọ fún wa láti ipaṣẹ̀ àwọn wòlíì ìrànṣẹ rẹ, nígbà ti ìwọ wí pé ilẹ̀ ti ẹ̀yin ń wọ̀ lọ láti lọ gbà jẹ́ ilẹ̀ tí ó di àìmọ̀ pẹ̀lú ìwà ìbàjẹ́ àwọn ènìyàn rẹ, nípa ṣíṣe ohun ìríra ilẹ̀ náà ti kún fún ohun àìmọ́ láti igun kan dé ìkejì.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 9

Wo Ẹ́sírà 9:11 ni o tọ