Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, kí ìwọ kí ó kó fàdákà àti wúrà lọ pẹ̀lú rẹ èyí tí ọba àti àwọn ìgbìmọ̀ rẹ fi tọkàntọkàn fún Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí ibùjókòó rẹ̀ wà ní Jérúsálẹ́mù,

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:15 ni o tọ