Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba àti àwọn ìgbìmọ̀ rẹ̀ méjèèjè rán ọ lọ láti wádìí nípa òfin Ọlọ́run rẹ tí ó wà ní ọwọ́ rẹ nípa Júdà àti Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 7

Wo Ẹ́sírà 7:14 ni o tọ