Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi àwọn àlùfáà sí àwọn ìpínsọ́wọ́ àti àwọn Léfì sì ẹgbẹẹgbẹ wọn fún ìsin ti Ọlọ́run ní Jérúsálẹ́mù, gẹ́gẹ́ bí ohun tí a kọ sínú ìwé Mósè.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:18 ni o tọ