Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún yíya ilé Ọlọ́run yìí sí mímọ́, wọ́n pa ọgọ́rùn-ún akọ màlúù (100), ọgọ́rùn-ún méjì àgbò (200) àti ọgọ́run mẹ́rin akọ ọ̀dọ́ àgùntàn (400), àti gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀ fún gbogbo Ísírẹ́lì, obúkọ méjìlá (12), ọ̀kọ̀ọ̀kan fún olúkúlùkù àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:17 ni o tọ