Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí Ọlọ́run, tí ó ti jẹ́ kí orúkọ rẹ̀ máa gbé ibẹ̀, kí ó pa gbogbo ọba àti orílẹ̀ èdè rún tí ó bá gbé ọwọ́ sókè láti yí àṣẹ yìí padà tàbí láti wó tẹ́ḿpìlì yìí tí ó wà ní Jérúsálẹ́mù ṣubú.Èmi Dáríúsì n pàṣẹ rẹ̀, jẹ́ kí ó di mímú ṣẹ láì yí ohunkóhun padà.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 6

Wo Ẹ́sírà 6:12 ni o tọ