Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọba kí ó mọ̀ pé a lọ sí ẹ̀kún Júdà, sí tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run alágbára. Àwọn ènìyàn náà ń kọ́ ọ pẹ̀lú àwọn òkúta ńlá ńlá àti pẹ̀lú fífi àwọn igi sí ara ògiri. Wọ́n ṣe iṣẹ́ náà pẹ̀lú àìsinmi, ó sì ń ní ìtẹ̀ṣíwájú kíákíá lábẹ́ ìṣàkóso wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 5

Wo Ẹ́sírà 5:8 ni o tọ