Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jérúsálẹ́mù ti ní àwọn ọba alágbára tí ń jọba lórí gbogbo àwọn agbégbé Yúfúrátè, àti àwọn owó orí, owó òde àti owó ibodè sì ni wọ́n ń san fún wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:20 ni o tọ