Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pa àṣẹ, a sì ṣe ìwádìí, nínú ìtàn ọjọ́ pípẹ́ àti ti ìsinsinyìí ti ìṣọ̀tẹ̀ sí àwọn ọba pẹ̀lú, ó sì jẹ́ ibi ìṣọ̀tẹ̀ àti ìrúkèrúdò.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 4

Wo Ẹ́sírà 4:19 ni o tọ