Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí ó ba kọ̀ láti jáde wá láàrin ọjọ́ mẹ́ta yóò pàdánù ohun ìní rẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú ìpinnu àwọn ìjòyè àti àwọn àgbààgbà, àti pé a ó lé òun fúnraaarẹ̀ jáde kúrò láàrin ìpéjọpọ̀ àwọn ìgbèkùn.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 10

Wo Ẹ́sírà 10:8 ni o tọ