Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní sinsin yìí, ẹ jẹ́ kí a dá májẹ̀mú níwájú Ọlọ́run wa láti lé àwọn obìnrin yìí àti àwọn ọmọ wọn lọ. Gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀ràn Ẹ́sírà Olúwa mi àti ti àwọn tí ó bẹ̀rù àṣẹ Olúwa Ọlọ́run wa. Ẹ jẹ́ kí a ṣe gẹ́gẹ́ bí òfin.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 10

Wo Ẹ́sírà 10:3 ni o tọ