Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Ṣékáníáyà ọmọ Jéhíélì, ọ̀kan lára ìran Élámù, sọ fún Ẹ́sírà pé, Àwa ti jẹ́ aláìsọ̀ọ́tọ́ sí Ọlọ́run wa nípa fífẹ́ àwọn obìnrin àjèjì láàrin àwọn ènìyàn tí ó wà yí wa ká. Ṣùgbọ́n ṣíbẹ̀ náà, ìrètí sì wà fún Ísírẹ́lì

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 10

Wo Ẹ́sírà 10:2 ni o tọ