Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ọmọbìnrin Síónì, ìjìyà rẹ yóò dópin;kò ní mú ìgbékùn rẹ pẹ́ mọ́.Ṣùgbọ́n, ìwọ ọmọbìnrin Édómù, yóò jẹ ẹ̀sẹ̀ rẹ níyàyóò sì fi àìṣedédé rẹ hàn kedere.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 4

Wo Ẹkún Jeremáyà 4:22 ni o tọ